2 Àwọn Ọba 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà náà, Méṣà ọba Móábù máa ń sin àgùntàn, ó sì máa ń fi ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) ọ̀dọ́ àgùntàn àti ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) akọ àgùntàn tí a kò rẹ́ irun wọn san ìṣákọ́lẹ̀* fún ọba Ísírẹ́lì. 1 Kíróníkà 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣẹ́gun Móábù,+ àwọn ọmọ Móábù wá di ìránṣẹ́ rẹ̀, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá.
4 Nígbà náà, Méṣà ọba Móábù máa ń sin àgùntàn, ó sì máa ń fi ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) ọ̀dọ́ àgùntàn àti ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) akọ àgùntàn tí a kò rẹ́ irun wọn san ìṣákọ́lẹ̀* fún ọba Ísírẹ́lì.