-
2 Sámúẹ́lì 19:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Gbogbo agbo ilé bàbá mi ni olúwa mi ọba ì bá ti pa, síbẹ̀ o ní kí ìránṣẹ́ rẹ wà lára àwọn tó ń jẹun nídìí tábìlì rẹ.+ Nítorí náà, ẹ̀tọ́ wo ni mo ní tí màá tún máa béèrè ohun míì lọ́wọ́ ọba?”
-