2 Sámúẹ́lì 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ẹgbẹ̀rún (1,000) ọkùnrin láti Bẹ́ńjámínì sì wà pẹ̀lú rẹ̀. Bákan náà, Síbà+ ẹmẹ̀wà* ilé Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15) pẹ̀lú ogún (20) ìránṣẹ́ sáré wá sí Jọ́dánì, wọ́n sì dé ibẹ̀ ṣáájú ọba.
17 ẹgbẹ̀rún (1,000) ọkùnrin láti Bẹ́ńjámínì sì wà pẹ̀lú rẹ̀. Bákan náà, Síbà+ ẹmẹ̀wà* ilé Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15) pẹ̀lú ogún (20) ìránṣẹ́ sáré wá sí Jọ́dánì, wọ́n sì dé ibẹ̀ ṣáájú ọba.