-
1 Kíróníkà 19:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìgbà náà ni Jóábù àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ jáde lọ pàdé àwọn ará Síríà lójú ogun, wọ́n sì sá kúrò níwájú rẹ̀.+ 15 Nígbà tí àwọn ọmọ Ámónì rí i pé àwọn ará Síríà ti fẹsẹ̀ fẹ, àwọn náà sá kúrò níwájú Ábíṣáì ẹ̀gbọ́n rẹ̀, wọ́n sì wọ inú ìlú lọ. Lẹ́yìn náà, Jóábù wá sí Jerúsálẹ́mù.
-