1 Kíróníkà 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* lákòókò tí àwọn ọba máa ń jáde ogun, Jóábù+ kó àwùjọ ọmọ ogun kan jáde, ó sì run ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì; ó wá dó ti Rábà,+ àmọ́ Dáfídì dúró sí Jerúsálẹ́mù.+ Jóábù gbéjà ko Rábà, ó sì wó o palẹ̀.+
20 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* lákòókò tí àwọn ọba máa ń jáde ogun, Jóábù+ kó àwùjọ ọmọ ogun kan jáde, ó sì run ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì; ó wá dó ti Rábà,+ àmọ́ Dáfídì dúró sí Jerúsálẹ́mù.+ Jóábù gbéjà ko Rábà, ó sì wó o palẹ̀.+