-
Àwọn Onídàájọ́ 6:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Torí náà, ó pe Gídíónì ní Jerubáálì* ní ọjọ́ yẹn, ó ní: “Jẹ́ kí Báálì gbèjà ara rẹ̀, torí ẹnì kan ti wó pẹpẹ rẹ̀.”