-
2 Sámúẹ́lì 11:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ó kọ ọ́ sínú lẹ́tà náà pé: “Ẹ fi Ùráyà síwájú níbi tí ogun ti le jù lọ. Lẹ́yìn náà kí ẹ pa dà lẹ́yìn rẹ̀, kí wọ́n lè mú un balẹ̀, kí ó sì kú.”+
-