2 Sámúẹ́lì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Láàárín àkókò yìí, Dáfídì bí àwọn ọmọkùnrin ní Hébúrónì.+ Ámínónì+ ni àkọ́bí tí Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì bí fún un.
2 Láàárín àkókò yìí, Dáfídì bí àwọn ọmọkùnrin ní Hébúrónì.+ Ámínónì+ ni àkọ́bí tí Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì bí fún un.