-
Òwe 26:24-26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ẹni tó kórìíra ẹlòmíì máa ń fi ọ̀rọ̀ ẹnu bò ó mọ́lẹ̀,
Àmọ́ ẹ̀tàn ló fi sínú.
25 Bó tilẹ̀ ń sọ ohun rere, má gbà á gbọ́,
Nítorí ohun ìríra méje ló wà lọ́kàn rẹ̀.*
26 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó fi ẹ̀tàn bo ìkórìíra rẹ̀ mọ́lẹ̀,
A ó tú ìwà burúkú rẹ̀ síta nínú ìjọ.
-