-
2 Sámúẹ́lì 14:1-3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nígbà náà, Jóábù ọmọ Seruáyà+ rí i pé ọkàn ọba ti ń fà sí Ábúsálómù.+ 2 Torí náà, Jóábù ránṣẹ́ sí ìlú Tékóà,+ ó pe ọlọ́gbọ́n obìnrin kan láti ibẹ̀, ó sì sọ fún un pé: “Jọ̀wọ́, ṣe bíi pé ò ń ṣọ̀fọ̀, kí o wọ aṣọ ọ̀fọ̀, má sì fi òróró para.+ Kí o ṣe bí obìnrin tó ti pẹ́ tó ti ń ṣọ̀fọ̀ ẹni tó kú. 3 Lẹ́yìn náà, kí o wọlé lọ bá ọba, kí o sì sọ ọ̀rọ̀ yìí fún un.” Ọ̀nà yẹn ni Jóábù gbà fi ọ̀rọ̀ sí obìnrin náà lẹ́nu.*
-