2 Sámúẹ́lì 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Obìnrin náà bá sọ pé: “Kí wá nìdí tí o fi gbèrò láti ṣe irú nǹkan yìí sí àwọn èèyàn Ọlọ́run?+ Nítorí o ti lé ọmọ rẹ kúrò láwùjọ,+ o kọ̀, o ò mú un pa dà, ohun tí o sọ yìí sì ti fi hàn pé ìwọ náà jẹ̀bi.
13 Obìnrin náà bá sọ pé: “Kí wá nìdí tí o fi gbèrò láti ṣe irú nǹkan yìí sí àwọn èèyàn Ọlọ́run?+ Nítorí o ti lé ọmọ rẹ kúrò láwùjọ,+ o kọ̀, o ò mú un pa dà, ohun tí o sọ yìí sì ti fi hàn pé ìwọ náà jẹ̀bi.