-
1 Sámúẹ́lì 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ta tiẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì ń lé kiri? Ta ni ò ń lépa? Ṣé òkú ajá bíi tèmi yìí ni? Àbí ẹyọ eégbọn kan ṣoṣo?+