-
Jẹ́nẹ́sísì 32:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Lẹ́yìn náà, Jékọ́bù ń bá tirẹ̀ lọ, àwọn áńgẹ́lì Ọlọ́run sì pàdé rẹ̀. 2 Gbàrà tí Jékọ́bù rí wọn, ó sọ pé: “Àgọ́ Ọlọ́run nìyí!” Torí náà, ó pe orúkọ ibẹ̀ ní Máhánáímù.*
-
-
Jóṣúà 13:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Bákan náà, Mósè pín ogún fún ẹ̀yà Gádì, àwọn ọmọ Gádì ní ìdílé-ìdílé,
-