Òwe 11:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ẹni* tó bá lawọ́ máa láásìkí,*+Ẹni tó bá sì ń mára tu àwọn míì,* ara máa tu òun náà.+