2 Sámúẹ́lì 21:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní kíá, Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà wá ràn án lọ́wọ́,+ ó ṣá Filísínì náà balẹ̀, ó sì pa á. Nígbà náà, àwọn ọkùnrin Dáfídì búra fún un pé: “O ò gbọ́dọ̀ bá wa lọ sójú ogun mọ́!+ Má ṣe jẹ́ kí iná Ísírẹ́lì kú!”+
17 Ní kíá, Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà wá ràn án lọ́wọ́,+ ó ṣá Filísínì náà balẹ̀, ó sì pa á. Nígbà náà, àwọn ọkùnrin Dáfídì búra fún un pé: “O ò gbọ́dọ̀ bá wa lọ sójú ogun mọ́!+ Má ṣe jẹ́ kí iná Ísírẹ́lì kú!”+