ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 22:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Àmọ́ ṣá, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Áhímélékì ọmọ Áhítúbù, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ábíátárì+ sá àsálà, ó sì lọ bá Dáfídì.

  • 1 Sámúẹ́lì 30:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìgbà náà ni Dáfídì sọ fún àlùfáà Ábíátárì+ ọmọ Áhímélékì pé: “Jọ̀wọ́, mú éfódì wá.”+ Torí náà, Ábíátárì mú éfódì wá fún Dáfídì.

  • 2 Sámúẹ́lì 15:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Sádókù+ wà níbẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ Léfì+ tí wọ́n ru àpótí+ májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́; wọ́n sì gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́+ kalẹ̀; Ábíátárì+ náà wà níbẹ̀ ní gbogbo àkókò tí àwọn èèyàn náà sọdá láti inú ìlú náà.

  • 1 Kíróníkà 15:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Yàtọ̀ síyẹn, Dáfídì pe àlùfáà Sádókù+ àti àlùfáà Ábíátárì+ àti àwọn ọmọ Léfì, ìyẹn Úríélì, Ásáyà, Jóẹ́lì, Ṣemáyà, Élíélì àti Ámínádábù, 12 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ni olórí agbo ilé àwọn ọmọ Léfì. Ẹ ya ara yín sí mímọ́, ẹ̀yin àti àwọn arákùnrin yín, kí ẹ sì gbé Àpótí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá sí ibi tí mo ti ṣètò sílẹ̀ fún un.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́