1 Àwọn Ọba 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Élíhóréfì àti Áhíjà, àwọn ọmọ Ṣíṣà ni akọ̀wé;+ Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù ni akọ̀wé ìrántí;