2 Sámúẹ́lì 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ìyàn+ kan mú nígbà ayé Dáfídì, ọdún mẹ́ta tẹ̀ léra ló sì fi mú. Nítorí náà Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, Jèhófà sì sọ pé: “Ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wà lórí Sọ́ọ̀lù àti lórí ilé rẹ̀, nítorí ó pa àwọn ará Gíbíónì.”+
21 Ìyàn+ kan mú nígbà ayé Dáfídì, ọdún mẹ́ta tẹ̀ léra ló sì fi mú. Nítorí náà Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, Jèhófà sì sọ pé: “Ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wà lórí Sọ́ọ̀lù àti lórí ilé rẹ̀, nítorí ó pa àwọn ará Gíbíónì.”+