Nọ́ńbà 25:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Mú gbogbo àwọn olórí* nínú àwọn èèyàn yìí, kí o sì gbé wọn kọ́ síwájú Jèhófà ní ọ̀sán gangan,* kí inú tó ń bí Jèhófà gidigidi sí Ísírẹ́lì lè rọlẹ̀.” Diutarónómì 21:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Tí ẹnì kan bá dẹ́ṣẹ̀, tó sì jẹ́ pé ikú ni ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ ti pa á,+ tí ẹ sì ti gbé e kọ́ sórí òpó igi,+
4 Torí náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Mú gbogbo àwọn olórí* nínú àwọn èèyàn yìí, kí o sì gbé wọn kọ́ síwájú Jèhófà ní ọ̀sán gangan,* kí inú tó ń bí Jèhófà gidigidi sí Ísírẹ́lì lè rọlẹ̀.”
22 “Tí ẹnì kan bá dẹ́ṣẹ̀, tó sì jẹ́ pé ikú ni ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ ti pa á,+ tí ẹ sì ti gbé e kọ́ sórí òpó igi,+