1 Kíróníkà 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn èyí, wọ́n bá àwọn Filísínì jà ní Gésérì. Ìgbà yẹn ni Síbékáì + ọmọ Húṣà pa Sípáì tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àtọmọdọ́mọ Réfáímù,+ wọ́n sì ṣẹ́gun àwọn Filísínì.
4 Lẹ́yìn èyí, wọ́n bá àwọn Filísínì jà ní Gésérì. Ìgbà yẹn ni Síbékáì + ọmọ Húṣà pa Sípáì tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àtọmọdọ́mọ Réfáímù,+ wọ́n sì ṣẹ́gun àwọn Filísínì.