2 Sámúẹ́lì 3:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó rẹ̀ mí lónìí yìí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n fòróró yàn mí ṣe ọba,+ ìwà àwọn ọkùnrin yìí, àwọn ọmọ Seruáyà,+ ti le jù fún mi.+ Kí Jèhófà san ibi pa dà fún ẹni tó ń hùwà ibi.”+
39 Ó rẹ̀ mí lónìí yìí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n fòróró yàn mí ṣe ọba,+ ìwà àwọn ọkùnrin yìí, àwọn ọmọ Seruáyà,+ ti le jù fún mi.+ Kí Jèhófà san ibi pa dà fún ẹni tó ń hùwà ibi.”+