2 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹni ogójì (40) ọdún ni Íṣí-bóṣétì, ọmọ Sọ́ọ̀lù nígbà tó jọba lórí Ísírẹ́lì, ó sì fi ọdún méjì ṣàkóso. Àmọ́ Dáfídì ni ilé Júdà ń tì lẹ́yìn.+
10 Ẹni ogójì (40) ọdún ni Íṣí-bóṣétì, ọmọ Sọ́ọ̀lù nígbà tó jọba lórí Ísírẹ́lì, ó sì fi ọdún méjì ṣàkóso. Àmọ́ Dáfídì ni ilé Júdà ń tì lẹ́yìn.+