Sáàmù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Á sọ pé: “Èmi fúnra mi ti fi ọba mi jẹ+Lórí Síónì,+ òkè mímọ́ mi.” Sáàmù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà, inú agbára rẹ ni ọba ti ń yọ̀;+Wo bí ó ṣe ń yọ̀ gidigidi nínú àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ!+