1 Sámúẹ́lì 25:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ti fi Míkálì+ ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ ìyàwó Dáfídì fún Pálítì+ ọmọ Láíṣì, tó wá láti Gálímù.