1 Kíróníkà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú nìyí: Jáṣóbéámù+ ọmọ ará Hákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin.+
11 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú nìyí: Jáṣóbéámù+ ọmọ ará Hákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin.+