Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jámútì, Ádúlámù,+ Sókọ̀, Ásékà,+ 1 Sámúẹ́lì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀,+ ó sì sá lọ sí ihò Ádúlámù.+ Nígbà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀ gbọ́, wọ́n lọ bá a níbẹ̀.
22 Nítorí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀,+ ó sì sá lọ sí ihò Ádúlámù.+ Nígbà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ àti gbogbo ilé bàbá rẹ̀ gbọ́, wọ́n lọ bá a níbẹ̀.