-
1 Sámúẹ́lì 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí náà, ó fi wọ́n sọ́dọ̀ ọba Móábù, wọ́n sì ń gbé lọ́dọ̀ rẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí Dáfídì fi wà ní ibi ààbò.+
-
-
1 Kíróníkà 12:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn kan lára àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì àti Júdà tún wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní ibi ààbò+ tó wà.
-