1 Sámúẹ́lì 22:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tó yá, wòlíì Gádì+ sọ fún Dáfídì pé: “Má ṣe gbé ní ibi ààbò mọ́. Lọ sí ilẹ̀ Júdà.”+ Torí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì lọ sí igbó Hérétì. 1 Kíróníkà 29:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran
5 Nígbà tó yá, wòlíì Gádì+ sọ fún Dáfídì pé: “Má ṣe gbé ní ibi ààbò mọ́. Lọ sí ilẹ̀ Júdà.”+ Torí náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì lọ sí igbó Hérétì.
29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran