2 Sámúẹ́lì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ Ábínérì+ ọmọ Nérì, olórí ọmọ ogun Sọ́ọ̀lù ti mú Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù sọdá sí Máhánáímù,+