-
2 Sámúẹ́lì 2:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àmọ́, ó kọ̀ kò dúró, torí náà Ábínérì fi ìdí ọ̀kọ̀ gún inú rẹ̀,+ ọ̀kọ̀ náà sì jáde ní ẹ̀yìn rẹ̀; ó ṣubú lulẹ̀, ó sì kú lójú ẹsẹ̀. Gbogbo ẹni tó dé ibi tí Ásáhélì ṣubú sí, tí ó sì kú sí, ló dúró tó sì ń wò.
-