ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 16:39, 40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Àlùfáà Sádókù+ àti àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ àlùfáà wà níwájú àgọ́ ìjọsìn Jèhófà ní ibi gíga tó wà ní Gíbíónì+ 40 láti máa rú àwọn ẹbọ sísun sí Jèhófà lórí pẹpẹ ẹbọ sísun déédéé, ní àárọ̀ àti ní ìrọ̀lẹ́ àti láti máa ṣe gbogbo ohun tó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Jèhófà tó pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+

  • 1 Kíróníkà 21:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àgọ́ ìjọsìn Jèhófà tí Mósè ṣe ní aginjù àti pẹpẹ ẹbọ sísun ṣì wà ní ibi gíga Gíbíónì+ ní àkókò yẹn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́