-
2 Kíróníkà 9:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Sólómọ́nì fi ogójì (40) ọdún jọba ní Jerúsálẹ́mù lórí gbogbo Ísírẹ́lì.
-
-
Oníwàásù 1:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Èmi, akónijọ, ló ti ń jọba lórí Ísírẹ́lì ní Jerúsálẹ́mù.+
-