-
1 Àwọn Ọba 1:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Níkẹyìn, Ádóníjà fi àgùntàn àti màlúù pẹ̀lú ẹran àbọ́sanra rúbọ+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkúta Sóhélétì, èyí tó wà nítòsí Ẹn-rógélì, ó pe gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àwọn ọmọ ọba àti gbogbo ọkùnrin Júdà tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ ọba. 10 Àmọ́ kò pe wòlíì Nátánì àti Bẹnáyà àti àwọn jagunjagun tó lákíkanjú, bẹ́ẹ̀ ni kò pe Sólómọ́nì àbúrò rẹ̀.
-