1 Àwọn Ọba 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí náà, ọrọ̀+ àti ọgbọ́n+ Ọba Sólómọ́nì pọ̀ ju ti gbogbo àwọn ọba yòókù láyé. 2 Kíróníkà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Fún mi ní ọgbọ́n àti ìmọ̀+ tí màá fi máa darí àwọn èèyàn yìí,* nítorí ta ló lè ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ tó pọ̀ yìí?”+ Òwe 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ ló ń fúnni ní ọgbọ́n;+Ẹnu rẹ̀ ni ìmọ̀ àti ìfòyemọ̀ ti ń wá.
10 Fún mi ní ọgbọ́n àti ìmọ̀+ tí màá fi máa darí àwọn èèyàn yìí,* nítorí ta ló lè ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ tó pọ̀ yìí?”+