-
Òwe 30:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ọ̀nà ẹyẹ idì lójú ọ̀run,
Ọ̀nà ejò lórí àpáta,
Ọ̀nà ọkọ̀ òkun lójú agbami,
Àti ọ̀nà ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀dọ́bìnrin.
-
19 Ọ̀nà ẹyẹ idì lójú ọ̀run,
Ọ̀nà ejò lórí àpáta,
Ọ̀nà ọkọ̀ òkun lójú agbami,
Àti ọ̀nà ọkùnrin pẹ̀lú ọ̀dọ́bìnrin.