-
Ìsíkíẹ́lì 27:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 kí o sì sọ fún Tírè pé,
‘Ìwọ tí ń gbé ní àwọn ẹnu ọ̀nà òkun,
Ò ń bá àwọn èèyàn láti ọ̀pọ̀ erékùṣù dòwò pọ̀,
Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:
“Ìwọ Tírè, o ti sọ pé, ‘Ẹwà mi ò lábùlà.’+
-