1 Àwọn Ọba 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Nígbà náà, Ọba Dáfídì ti darúgbó,+ ó ti lo ọ̀pọ̀ ọdún* láyé, bí wọ́n tiẹ̀ ń fi aṣọ bò ó, òtútù ṣì máa ń mú un. 1 Àwọn Ọba 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n wá ọmọbìnrin tó rẹwà kiri gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, wọ́n rí Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù,+ wọ́n sì mú un wá fún ọba.
1 Nígbà náà, Ọba Dáfídì ti darúgbó,+ ó ti lo ọ̀pọ̀ ọdún* láyé, bí wọ́n tiẹ̀ ń fi aṣọ bò ó, òtútù ṣì máa ń mú un.
3 Wọ́n wá ọmọbìnrin tó rẹwà kiri gbogbo ilẹ̀ Ísírẹ́lì, wọ́n rí Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù,+ wọ́n sì mú un wá fún ọba.