2 Kíróníkà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wò ó! Màá pèsè oúnjẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ,+ àwọn agégi tó máa gé igi náà, màá fún wọn ní: ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀* àlìkámà,* ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀ ọkà bálì, ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì* wáìnì àti ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì òróró.”
10 Wò ó! Màá pèsè oúnjẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ,+ àwọn agégi tó máa gé igi náà, màá fún wọn ní: ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀* àlìkámà,* ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀ ọkà bálì, ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì* wáìnì àti ọ̀kẹ́ kan (20,000) báàtì òróró.”