-
Ẹ́kísódù 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Kí ẹ máa rántí ọjọ́ yìí, kí ẹ sì máa ṣe ayẹyẹ rẹ̀, kó jẹ́ àjọyọ̀ sí Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín. Ẹ máa pa àjọyọ̀ náà mọ́, ó ti di òfin fún yín títí láé.
-
-
Ẹ́kísódù 12:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Ọjọ́ yìí gan-an ni Jèhófà mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn* kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
-