2 Kíróníkà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ibi àbáwọlé* tó wà níwájú jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó bá fífẹ̀ ilé náà mu,* gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́; * ó wá fi ògidì wúrà bò ó nínú.+
4 Ibi àbáwọlé* tó wà níwájú jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó bá fífẹ̀ ilé náà mu,* gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́; * ó wá fi ògidì wúrà bò ó nínú.+