-
1 Àwọn Ọba 6:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó kọ́ àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ yí ilé náà ká,+ gíga ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, àwọn gẹdú igi kédárì ni ó sì fi mú wọn mọ́ ara ilé náà.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 41:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ó wá wọn ògiri tẹ́ńpìlì náà, ìnípọn rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà. Fífẹ̀ àwọn yàrá tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ tẹ́ńpìlì náà yí ká jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin.+
-