1 Àwọn Ọba 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+
7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+