-
Ẹ́kísódù 25:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Iṣẹ́ ọnà mẹ́ta tó rí bí òdòdó álímọ́ńdì ni kó wà lára àwọn ẹ̀ka tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kan, kí kókó rubutu àti ìtànná kọ̀ọ̀kan tẹ̀ léra, kí iṣẹ́ ọnà mẹ́ta tó rí bí òdòdó álímọ́ńdì sì wà lára àwọn ẹ̀ka tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kejì, kí kókó rubutu àti ìtànná kọ̀ọ̀kan sì tẹ̀ léra. Bí ẹ̀ka mẹ́fẹ̀ẹ̀fà ṣe máa yọ jáde lára ọ̀pá fìtílà náà nìyí.
-