1 Àwọn Ọba 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó fi pátákó kédárì ṣe apá kan tí ó jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ sí ẹ̀yìn ilé náà, láti ìsàlẹ̀ ilé náà títí dé àwọn igi ìrólé, ó sì kọ́ Ibi Mímọ́ Jù Lọ+ sínú rẹ̀,* èyí ni yàrá inú lọ́hùn-ún.+
16 Ó fi pátákó kédárì ṣe apá kan tí ó jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ sí ẹ̀yìn ilé náà, láti ìsàlẹ̀ ilé náà títí dé àwọn igi ìrólé, ó sì kọ́ Ibi Mímọ́ Jù Lọ+ sínú rẹ̀,* èyí ni yàrá inú lọ́hùn-ún.+