2 Kíróníkà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó ṣe àwọn òpó náà síwájú tẹ́ńpìlì, ọ̀kan sápá ọ̀tún,* èkejì sápá òsì;* ó pe èyí tó wà lápá ọ̀tún ní Jákínì* àti èyí tó wà lápá òsì ní Bóásì.*
17 Ó ṣe àwọn òpó náà síwájú tẹ́ńpìlì, ọ̀kan sápá ọ̀tún,* èkejì sápá òsì;* ó pe èyí tó wà lápá ọ̀tún ní Jákínì* àti èyí tó wà lápá òsì ní Bóásì.*