Ìsíkíẹ́lì 41:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ojú èèyàn kọjú sí àwòrán igi ọ̀pẹ ní ẹ̀gbẹ́ kan, ojú kìnnìún* sì kọjú sí àwòrán igi ọ̀pẹ ní ẹ̀gbẹ́ kejì.+ Bí wọ́n ṣe gbẹ́ ẹ sí ara tẹ́ńpìlì náà yí ká nìyẹn.
19 Ojú èèyàn kọjú sí àwòrán igi ọ̀pẹ ní ẹ̀gbẹ́ kan, ojú kìnnìún* sì kọjú sí àwòrán igi ọ̀pẹ ní ẹ̀gbẹ́ kejì.+ Bí wọ́n ṣe gbẹ́ ẹ sí ara tẹ́ńpìlì náà yí ká nìyẹn.