-
1 Àwọn Ọba 6:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ó fi igi ahóyaya ṣe ilẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà yàrá inú lọ́hùn-ún, ó tún fi ṣe àwọn òpó ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ àti àwọn òpó ilẹ̀kùn, ó jẹ́ ìdá márùn-ún* ògiri náà.
-