1 Àwọn Ọba 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà á sì mú ìlérí tó ṣe nípa mi ṣẹ, pé: ‘Bí àwọn ọmọ rẹ bá fiyè sí ọ̀nà wọn, láti fi òtítọ́ rìn níwájú mi pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn àti gbogbo ara* wọn,+ kò ní ṣàìsí ọkùnrin kan láti ìlà ìdílé rẹ* tí yóò máa jókòó sórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.’+ Sáàmù 132:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+
4 Jèhófà á sì mú ìlérí tó ṣe nípa mi ṣẹ, pé: ‘Bí àwọn ọmọ rẹ bá fiyè sí ọ̀nà wọn, láti fi òtítọ́ rìn níwájú mi pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn àti gbogbo ara* wọn,+ kò ní ṣàìsí ọkùnrin kan láti ìlà ìdílé rẹ* tí yóò máa jókòó sórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.’+
12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+Àwọn ọmọ tiwọn náàYóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+