Ìsíkíẹ́lì 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ọmọ èèyàn, tí ilẹ̀ kan bá hùwà àìṣòótọ́ tó sì wá ṣẹ̀ mí, màá na ọwọ́ mi kí n lè fìyà jẹ ẹ́, màá sì dáwọ́ oúnjẹ rẹ̀ dúró.*+ Màá mú kí ìyàn mú níbẹ̀,+ màá sì pa èèyàn àti ẹranko inú rẹ̀ run.”+
13 “Ọmọ èèyàn, tí ilẹ̀ kan bá hùwà àìṣòótọ́ tó sì wá ṣẹ̀ mí, màá na ọwọ́ mi kí n lè fìyà jẹ ẹ́, màá sì dáwọ́ oúnjẹ rẹ̀ dúró.*+ Màá mú kí ìyàn mú níbẹ̀,+ màá sì pa èèyàn àti ẹranko inú rẹ̀ run.”+