1 Kíróníkà 27:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Olórí àwùjọ kẹta tí wọ́n yàn láti ṣiṣẹ́ ní oṣù kẹta ni Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ olórí àlùfáà, ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ rẹ̀.
5 Olórí àwùjọ kẹta tí wọ́n yàn láti ṣiṣẹ́ ní oṣù kẹta ni Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ olórí àlùfáà, ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ rẹ̀.